Àwọn Áràbù, pàápàá àwọn èyí tó ń gbé ní ìlú Dearborn, le mú àyípadà bá èsì ìbò ọdún yìí ní àwọn ìlú tí ìbò wọn kìí nípa ...
Ní ilẹ̀ Áfíríkà nìkan, ìjábọ̀ ní obìnrin tó lé ní mílíọ̀nù ogóje ló dábẹ́ èyí táwọn olóyìnbó ń pè ní Femal Genital Mutilation ...
Ohun tí èyí túmọ̀ sí ni pé tí èèyàn bá fẹ́ gba ìwé ìrìnnà, ònítọ̀hún kò ní nílò láti dé iléeṣẹ́ wọn, orí ayélujára ni yóò ti ...
Ní ọjọ́ Kẹtàdínlọ́gbọ̀n, oṣù Kejìlá, ọdún 2023 ni Ganiyat Popoola àti ọkọ̀ rẹ̀, Nurudeen Popoola pẹ̀lú ọmọ ẹ̀gbọ́n rẹ̀ kan, ...
Ẹ̀sùn tí Iba Gani Adams fi kan Sunday Igboho ni pé ó ká ohun òun sílẹ̀ lásìkò tí òun ń bá èèyàn kan sọ̀rọ̀ lórí fóònù láì gba ...
Àwọn ìdìbò lórí ayélujára ń ṣàfihàn pé ìyàtọ́ díẹ̀ ló wà láàárín Kamala Harris, igbákejì ààrẹ Amẹ́ríkà tó ń díje sípò ààrẹ ...
Ní nǹkan bíi aago mẹ́sàn-án òwúrọ̀ ni ètò ìdìbò ti bẹ̀rẹ̀ káàkiri ìpínlẹ̀ náà táwọn èèyàn sì jáde lọ dìbò pàápàá ní àwọn ìlú ...
Ṣé àwọn ẹ̀yà polio tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ fojú hàn ni Pakistan ati Afghanistan yóò jẹ́ kí àlá WHO láti fòpin sí àìsàn náà wá sí ìmúṣẹ ...
Ó ní ó ṣe pàtàkì kí ìran Áfíríkà le máa sọ ìtàn ara wọn fúnra wọn látara sinimá àti pé èyí wà lára ohun tó ń fún òun ní ìwúrí ...
Harris, tó ń díje sípò Ààrẹ lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú Democrat sọ̀rọ̀ nípa ìtàkurọ̀sọ tó wáyé láàárín Trump àti Ààrẹ Joe Biden, kó tó ...
Iléeṣẹ́ ìròyìn Niger kéde pé Hamma, ẹni tó ti fìgbà kan rí jẹ́ Abẹnugan ilé aṣòfin, jáde láyé lẹ́yìn tó ń gba ìwòsàn ní ilé ...
Thèid na Fir-thàileisg a chur ann am bogsa glainne gus an gabhadh faicinn bho gach taobh airson a' chiad uair.